en
stringlengths 5
934
| yo
stringlengths 4
1.13k
|
|---|---|
Just kidding!
|
Ó kan ńṣeré lásán!
|
Kandyan drummers led the accused war criminal to the site where he laid the foundation stone.
|
Àwọn onílù Kandyan ni wọ́n ṣaájú àwọn ẹni afẹ̀sù ogun kan náà lọ sí ibi tí wọ́n ti fi okúta ogunlé náà lélẹ̀.
|
This one quote made me realize it is my responsibility to try to restore that bridge between us.
|
Ọ̀rọ̀ àsọ́ọ́lẹ̀ ẹni yìí jẹ́ kin mọ̀ pé, ẹ̀tọ́ mi ni láti yanjú aáwọ̀ tó wà láàárín wa.
|
The advanced artificial intelligence displayed by Assistant is impressive.
|
Ìmọ ẹ̀rọ àgbélẹ̀rọ tó ga tí Assistant náà se wúni lórí.
|
Ministry officials, governmental agencies, regulatory authorities, and civil society organizations.
|
Àwọn òṣìṣẹ́ alákòóso ìjọba, àwọn ile iṣẹ́ ìjọba, àwọn aláṣẹ olútọ̀sọ́nà àti àwọn àjọ inú awùjọ.
|
And for that I am embarrassed, and disappointed, and angry.
|
Àti fún ìyẹn ojú gbà mí tì, mo níjàákulẹ̀, mo sì bínú.
|
Oh no, is everything alright, Latasha replied in a concerned tone?
|
Ha, ṣe kò sí ìyọnu, Latasha dáhùn pẹ̀lú ohùn pé ọ̀rọ̀ náà kàn-án?
|
The patient was successfully treated with surgical drainage and antibiotic administration.
|
Wọ́n ṣe ìtọ́jú aláìsàn náà láṣeyọrí pẹ̀lú surgical drainage àti ìṣàkóso ogun-abárùnjà.
|
The introduction of a rigid salary ceiling, with exceptions for one or two star players;
|
Ìṣàfihàn òté fún owó oṣù aláìyídà, pẹ̀lú ìfàyègbà fún ọ̀kan tàbí méjì àwọn agbábọ́ọ̀lù tó fakọyọ;
|
In 2001, Chris joined the family business, where he served as a sales representative for five years.
|
Ní 2001, Chris darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ ìdílé, níbi tó ti ṣiṣẹ́ bíi atajà fún ọdún márùn-ún.
|
To accomplish such a great task against long odds will require a highly diverse and efficient organization.
|
Láti ṣe àṣeyọrí irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú àìmọ̀ tó pọ̀ yóò nílò ilé-iṣẹ́ tó ṣiṣẹ́ dáradára.
|
It is going to give you such an immense reward, such tremendous satisfaction as an artist.
|
Yóò fún ọ nỉ èrè ńlá, irúfẹ́ ìgbáláńdùn bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ayàwòrán.
|
Federal agents conducted additional searches across Florida.
|
Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tún ti ṣe wíwá kárí Florida.
|
When lead singer Sting wrote the song, he was dealing with jealousy and obsession during the collapse of his marriage.
|
Nígbà tí adarí olórin Sting kọ orin náà, ó nbá bá owú jà àti ìdánú nígbà tí ìgbéyàwó rẹ̀ forí ṣánpọ́n.
|
The documents indicated that Ford was involved in funding a suite of classes for institutions like "Para Nosotras".
|
Àwọn ìwé náà fi hàn pé Ford wà lára àwọn tó kówó sílẹ̀ láti ṣe ẹjó fún àwọn iléèwé bí i "Para Nosotras".
|
Knowing and maintaining code is critical for maximum fire protection.
|
Mímọ̀ àti ṣíṣàmójútó kóòdò jẹ́ ìdáàbòbò iná tó le.
|
Then came the implementation phase again; I wanted a perfect automation process, coding style, following framework rules etc;
|
Ó tú wá pèlú abala ìmúṣẹ́ ṣe; mo fẹ́ ìgbésẹ̀ àdáṣiṣẹ́ tó dára jùlọ, sítàìlì kóòdù, títẹ̀lé àwọn ìlànà òfin;
|
With that huge and innocent smile, this chick is cute as hell!
|
Pẹ̀lú èrín ńlá yẹn, ọmọ yìn rẹwà púpọ̀!
|
His deep concern for those whose family members suffered death suddenly.
|
qÌkẹ́dùn rẹ̀ fún àwọn tí ẹbí wọn kú ikú òjijì.
|
Lisa found peace from electro-pollution by moving to an off-grid cottage in the Swedish countryside with her family.
|
Lisa rí ìbàlẹ̀-ọkàn látara òórùn-ajẹmọ́ná nípa lílọ sí ilé tí kò sí lórí iná ní ìlú Sweden pẹ̀lú àwọn ẹbí rẹ̀.
|
Royal Rangers is a christian scouting program designed to minister to the needs of boys.
|
Royal Rangers jẹ́ ètò ìwáni ti kìrìsìtẹ́nì tí a dá sílẹ̀ láti máa rí sí ìní àwọn ọmọdékùnrin.
|
Ponder what scenarios might evolve that breach your ability to absorb negative impact or exploit risks.
|
Ronu nípa ohun tó lè ṣẹlẹ̀ tó lè mú kí o má lè gba ohun burúkú tàbí ṣèwòye ohun líle.
|
An important part of my identity is my indigenous heritage, and our connection with birds like the crow and raven.
|
Lára ìdámọ̀ mi tó ṣe pàtàkì ni ìdámọ̀ orísun mi, àti ìbáṣe wa pẹ̀lú àwọn ẹyẹ bíi eyelé àti ìwò.
|
These wives can be the most loving, loyal, tender, and caring individuals.
|
Àwọn ìyàwó wọ̀nyí lè di nínífẹ̀ẹ́ púpọ̀, ṣíṣìkẹ́, àti onítọ̀ọ́jú ènìyàn.
|
Do they follow the usual internship timeline, and if not, can you give an estimate about the hiring timeline?
|
Ṣé wọ́n tẹ̀lé àsìko ìkóṣẹ́ bó ti máa ń ṣe, bí bẹ́ẹ̀kọ́, ṣé o lè ṣe ìwòye-àsìkò nípa àsìko ìgbanisíṣẹ́?
|
Following the government’s announcement, Tencent issued a public pledge to amend its privacy statements.
|
Ní àtẹlé sí ìkéde ti ìjọba náà, Tencent gbé ẹ̀jẹ́ ti gbogbogbòò kan jáde láti ṣàtúnṣe sí àwọn gbólóhùn ìkọ̀kọ̀ rẹ̀.
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.