text
stringlengths 32
135
| audio
audioduration (s) 3.43
14.8
| speaker_id
stringclasses 1
value | age_group
stringclasses 1
value | domain
stringclasses 1
value | gender
stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
lẹyìn [um] tí ó jogún òbítibitì owó lọwọ àǹtí rẹ ó ní ifọkanbalẹ lórí ìṣúná rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn alágbẹdẹ sàgbéyẹwò àǹfààní àti àléébù níbí nínáwó sí ìdógò wọn sí
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
léyìn ìsèrá eni ní gbogb ààrín sè òpò ènìyàn ni ó [um] máá ná [um] máá ná owó ní ìnákùná ní òpin òsè
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ṣíṣàgbékalẹ owó pàjáwìrì nípasẹ [um] ìfowópamọ [um] déédé máa n ṣèrànwọ láti dènà wàhálà owó lásìkò ìnáwó àìròtẹlẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àjọ tó ń bójú tó ríra nǹkan ni àwìn pèsè àwọn olùdámọràn tó ní orúkọ rere káàkiri àgbáyé
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn onílé [um] máá mú ọjó kan pàtó tí wón retí kí ayálégbé san owò ilé
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìwà ìṣúná tó lọgbọn ni kí èèyàn rà nǹkan aloku dípò ríra nǹkan tuntun
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
banki ìpamọ ti zimbabwe kò yí òṣuwọn ìṣúnná owó padà
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
dídé ìdá kẹrin nínú ìfipamọ máa ń ìfipamọ máa ń mú ìwúrí bá ènìyàn láti tẹsíwájú lórí ètò kíkóaraẹniniìjánu nípa ìṣúná
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
olùṣàkóso ilé ìtajà náà kò lè kọ ohùn ẹbẹ oníbàárà náà o sì fun ni ẹdínwó ìdá méwàá nínú ọgọrùnún
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
òṣìṣẹ aṣojú oníbàárà farabalẹ ṣe ìwádìí àìṣedéédé náà nínú owó rẹ tó fi ránṣẹ láti yanjú ọrọ náà
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
fí fí àwọn ináwó pajawiri sọtọ pẹlú àwọn ináwó oṣù mẹta sí mẹfà ṣe iranlọwọ láti dín wahalà ináwó ku
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọlọpọ àwọn àgògò ni wọn ń darí owóòwò sí àwọn owó ìfẹhìntì àwọn òbí wọn àti àwọn ináwó ìgbésíayé wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ṣíṣètò ilépa ìṣúná kan bíi rira ilé máa ń fa ìpinnu ìdókòwò ọjọ pípẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
o tiraka látí ṣètò ìnáwó rẹ nitori àìláyọlé iṣẹ àkànṣe olómìnira rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ẹni tó n ṣọ owó ná máa n fi ìdá kan nínú owó oṣù wọn sọrí owó ètò jápá
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn òṣìṣẹ ẹlẹgbẹ kójọ sí ọfísì láti ṣàjọpín àseyọrí ìdókòwò wọn nígbà oúnjẹ ọsán
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
lílọra láti sọrọ owó tó ń wọlé fún ṣokùnfà àṣírí tí kò yẹ nípa ipò ìṣúná rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn àsẹsẹgbéyàwó náà mu àpòowó ìfowópamọ alájọni lọkùnúnkúndùn nípasẹ mímú ìlépa owó wọn ṣe rẹgí pẹlú májẹmú ìgbeyàwó wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìlànà ètò ìṣúná pínpín tọkọtaya pínpín tọkọtaya náà ṣe iranlọwọ fún wọn láti san gbèsè káàdì kirẹditi wọn ní oṣù mẹfà
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
bí agbaye bí agbaye ṣe [um] ń bèrè ohun àlùmọnì inú ilẹ ṣe ń pọsi ìdíyelé ń [um] lọ sókè nítorí gbèdéke ìgbéjáde
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àṣeyọrí ìlò ẹrọ wọlẹtì onínọmbà jẹ kí ó rọrùn láti ṣàbójútó ìṣúná àti ìdínkù ìnáwó dáadáa
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
lẹyìn tí ó ṣe àyèwò ó rí pé òun kùnà ilépa ìṣúná ọlọjọpípẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
olùtajà náà lo ìdá púpọ nínú owó rẹ láti fi ra owó ìpè aláfojúsùn tó dára
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
owó ẹrọ onínọmbà bíi cryptocurrencies ń ṣe ààbò fún ìdúnadúrà láìsí pé ènìyàn kó owó náà dání
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
bí ọrọ ajé ìgbaṣẹṣe ṣe gbòòrò ọpọlọpọ àwọn akọṣẹmọṣẹ ló yíjú sí ìgbaṣẹṣe gẹgẹ bí ọnà mìíràn láti rí owó
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọ ilé ló n ṣètò ìdá mẹwàá nínú owó tó n wọlé fún wọn lọdún fún ìnáwó oúnjẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
zimbabwe iye owó tó ń wọlé lóṣooṣù ń wálẹ fún ìgbà kẹrin gbáko
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìsanwó ọlọsẹméjì ń pèsè ìpìlẹ fún ìdúróṣinṣin ìṣúná fún ọpọlọpọ ẹnìyàn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ṣíṣèdá owó ìpamọ pajawìrì ń fúnni ní ààbò ìṣúná lójú ìnawo àìròtẹlẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn ìgbìyànjú rẹ láti ṣètò àbá ìṣúná tó dúró ṣinṣin nítorí ìrísí iṣẹ agbaṣẹṣe rẹ tí kò ṣe é sọtẹlẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
bíbá ẹlòmíràn yá owó láìsí ìṣètò isanpada gidi lè fa ìṣòro ìṣúná
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
yíya ọrẹ tàbí ẹbí ní owó láìsí ìṣètò isanpada kún fún ewu
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àyàwòrán náà se ìdúnàádúrà dáradára láti yàgò fún àìsanwó pe fún iṣẹ àtinúdá rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìsanwó ayélujára tí ileifowopamo ṣàfihàn ìdúnadúrà náà bí èyí tí wọn fura si ó sì nílò ijerisi síwájú sí i
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìyàtọ nínú àṣà owó níná níná àwọn lọkọláya náà sábà máa n fa àwọn ìtàkurọsọ líle nínú ilé wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn olùdókòwò sábà máa ń yà ida mewa sí medogun ti owóoṣù wọn fún fífipamọ ifẹyinti ọdọdún
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọdó alámọṣẹdájú máa ń fi kirẹditi fóònù tí a ti san tẹlẹ ránṣẹ sí àwọn ọmọ ìyá rẹ ni òkèèrè
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
owó àwọn òògùn tí ó pọ sí jẹ ẹrù ináwó pàtàkì lórí púpọ nínú àwọn ìdílé amẹrika
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àìtètédáhùn eni tí a fi owó ránsé sí sí ìjà náà fa ìdàmú pèlú owó tí a fi ránsè
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọlọpọ àwọn ìdílé ló n làkàkà láti mójútó bùkátà owó iléìwé aládáni lọdọọdún to n waye ni gbogbo igba
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
aṣojú ẹka ìtajà fún mi ní ẹdínwó ìdá mẹwàá nínú ọgọrùnún fún rira ọjà púpọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
owó ìṣúra ilé iṣẹ náà [um] já [um] já wálẹ lójijì lẹyìn tí àtẹ káràkátà [um] ayélujára wọn kojú ìṣòro ẹrọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìdílé náà farabalẹ ṣe ìwòn àwọn ànfààní àti àìlànfààní tí ìsọdótún ìyàló wọn dípò wíwá àwọn aṣàyàn ilé tuntun
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìwádìí náà jé àtúnyèwò [um] àwọn àwọn ọjà kò sì jẹ ìgbésẹ ìdámọràn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àyè iṣẹ olómìnira náà pèsè ètò ìsanwó ìrọrùn títí kan sí sanwó púpọ lẹkan tàbí ní wákàtí kọkan
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọ ènìyàn mú dídá owó sọtọ fún nnkan pàjáwìrì fún àwọn ìnáwó àìròtẹlẹ bíi ìsìnkú
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìfitónilétí ìwọlé iléìfowópamọ tó fura sí ló jẹ kó tètè ṣe ààbò fún àpò owó ayélujára rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
owó tó pọ tó wọlé ló jẹ kí lè ra ẹrọ ibánisọrọ gidi
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
iléiṣẹ àpapọ orílẹèdè fún ìmòràn lórí sísan gbèsè ń pèsè iṣẹìgbanímọràn olówópọọkú fún àwọn ènìyàn káàkiri orílẹèdè
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ó máa ń ṣe gbéga ìlàkàkà ìnáwó ọrẹ rẹ jú ìfowópamọ tirẹ lọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọlọpọ àwọn òbí ló n tiraka láti gbìyànjú lo owó ìyàsọtọ ọlọdọọdún fún ẹkọ bí i ti àwọn owó sáà
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àìní ìṣúná tó dára ẹgbẹ náà fa àríyànjiyàn lórí ètò isanpada owó tí wón yá
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ó fẹsọ sàtúnyẹwò àkọsílẹ owó tó wà ní iléìfowópamọ rẹ láti sàridájú rìsíìtì nkán tórà láìpẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
bí ó ṣe bẹrẹ sí ní gbaṣẹṣe òmìnira ìṣúná rẹ bù kún àpapọ ìdánilójúara ẹni àti agbára ìpinnu ṣíṣe rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ṣíṣe àfiwé àfihàn oríire owó níní àwọn ọrẹ lórí gbàgede ayélujára ní gbogbo ìgbà lágbára púpọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
láàrin ọrọajé tó dẹnu kọlẹ àwọn ọlọgbọn ènìyàn máa n yan díndín gbèsè kù láàyò ju ìdókòwò ọjọiwájú lọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn olùdókòwò atẹẹjẹjẹ gbọdọ ṣàyẹwò fínnífínní orúkọ rere àti àwọn ìrísí ààbò ikanniikowosi náà kí wọn tó ṣe káràkátà
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ẹgbẹ́ àbójútó oníbàárà tí ilé-ìfowópamọ́ náà yà sọ́tọ̀ máa ń ṣèrànwọ́ láti yanjú àwọn àṣìṣe tó díjú nínú àkọsílẹ̀
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọ àwọn amòye owó dábàá yíya ìdá mẹwàá owo oṣù ẹni sọtọ fún àwọn ìlépa ìfowópamọ ọjọ iwáju
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọ àwọn òṣìṣẹfẹyìntì ló gbọkànlé àpòowó wọn láti rí owó ná lẹyìn tí wọn fẹyìntì
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ìlọsókè ìbéèrèfún àwọn ohunèlò ìgbádùn jẹ kí owó ọjà lọ sókè lójijì ní ọjà àgbáyé
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
kò tó kí á yá owó pèlú èlé tí ó ju owó osù ẹni lọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn olùdókòwò máa n tilẹ ṣàfitì ìdá ogún nínú ọgọrùún nínú èrè wọn síbi ìfowópamọ onígbà pípẹ fún ìfẹhìntì wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn ìsòro iṣẹẹrọ iléiṣé náà fà ìpàdánù ìtàjà ìdá méjì nínú ìdá ọgọrùnún lún
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àìlọsókè owó oṣù rẹ jẹ kí ó rí ara rẹ bí ẹni tí kò níyì pẹlú gbogbo ìgbìyànjú rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn èrònjà iná mànàmáná wà ní iléìtajà aládúgbò wa ní èdínwó púpọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
fífi owó kéékèèké pamọ déédéé lójoojúmọ máa ń yọrí sí ìdàgbàsókè ìṣúná
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ṣíṣe àbójútó sì sanwó lóṣooṣù lè jẹ orísun ìpayà fún ìṣúná
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
oníṣòwò náà ṣe àyẹwò pẹkipẹki itan ìṣòwò iléiṣẹ rẹ láti tọpa ináwó àti láti mọ àwọn àìlera
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
owó gọbọi tí [um] wọn dá lé aagoọwọ náà kò jẹ kí ó wu àwọn oníbàárà tó ń ṣọ owó ná
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọ ènìyàn ló ń rí ìpéjọpọ bíi iṣẹ bi olùdámọràn nerdwallet wúlò nínú ṣíṣe ìpinnu lóró ìdókòwò
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àṣẹ náà tún pàṣẹ fún àwọn iléifowopamọ láti má ṣe ṣe àwọn ìnáwó ìṣòwò cryptocurrency
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ó fárá balẹ ṣàtúnyẹwò àwọn ìnáwó rẹ láti rí i dájú pé àwọn olùpèsè iṣẹ kò gba elé lọwọ rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọlọpọ ènìyàn ń tiraka láti bèrè [um] ìrànlọwọ owó lọdọ ará owó lọdọ ará wọn nítorí ìtìjú
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ẹbùn owó àìnírètí láti ibi àsanpadà owóorí fún mi láàyè láti ṣe ìgbésókè owó pàjáwìrì mi
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
owó oṣù òǹkọwé [um] àtiléṣiṣẹ náà [?] dá [um] lórí iye iṣẹ tó bá parí rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn òbí àgbà náà lo ọgbọn láti fi ogún àwọn ọmọọmọ wọn dókòwò nínú àsùnwọn ìdókòwò ọlọkanòjọkan oníṣùúra àti owóyàá
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọlọpọ ènìyàn gbọkànlé gbigba owó nlá ní ẹẹkanna ti ètò ọjà àlàkalẹ láti ọdọ agbanisíṣẹ wọn tàbí
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn òbí tuntun lè pín ẹgbèrun márùnún dọlà [um] nínú owó tó wọlé [um] fún wọn lọdọọdún fún àwọn ináwó ìbímọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ẹbí smith farabalẹ ṣe ìwọn ìwọn àǹfààní àti àléébù àwọn ìdógò wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
onílé náà farabalẹ ro àwọn àṣàyàn ìnáwó láti dènà kí kọjá òdiwọn ọjà àwìn rírà wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọlọpọ ènìyàn ṣàṣeyọrí lórí ìṣúná nípa gbígbéṣájú àwọn ohun tí wón nílò ohun tí wọn fẹ lọ ni oṣu kọọkan
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn òbí tuntun náà ná nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta dọ́là lórí ayẹyẹ ìsọmọlórúkọ náà
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
yíyá owó lọwọ àwọn mọlẹbí sábà máa ń yọrí sí ìdára eni lẹbi àtí àìdára ẹni lójú lẹyìn ìgbà náà
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ẹbi ọkàn fífi gbogbo nínáwo pẹlú ìrọrùn sílẹ fún àwọn olólùfẹ ẹni nílò ìwọ gidi
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
fífi idà ogún pamọ nínú owó oṣù fún ilépa ìṣúná ìgbàpípẹ ṣe kókó
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọ [um] ènìyàn máa ń fi fífowóṣùn àti ìdókòwò ṣáájú láti le ṣàṣeyọrí ọlójóó gbooro pẹlú ètò ìsúná wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
lẹyìn iṣọkan àwọn gbèsè àti ṣiṣẹda ìṣúná ó padà ní ìdúróṣinṣin nínú ìṣúná
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ṣíṣètò ìlànà atúnyẹwò ni oṣooṣù ń ṣe ìrànlọwọ fún àwọn ènìyàn láti dúró lórí àṣàrò ìnáwó wọn déédéé
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
bí ìwòn èlé se pọ o yẹ kí ọrẹ mí yẹra fún ìpèsè gbèsè alàdáni tó ní ewu púpọ yẹn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ọpọ òṣìṣẹ gbarale gbígba ifowóránṣẹ to pọ lọwọ agbanisíṣẹ wọn láti lè ṣàbójútó ìṣúná ti ara wọn dáadáa
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn ohunèlò ìṣúná owó bíi mint máa ń ṣe ṣe ìtọnà fún olùmúlò nípa níná àti ṣíṣé ìtọjú owó wọn
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
iweowó iṣoogun àìròtẹlẹ fi agbára mú u láti fíbọ sínú owó ìfowópamọ pajàwìrí rẹ ní kíákíá
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àwọn eré àṣà ìbílẹ bù kún ìnáwó ìkómọ náà gidigidi lápapọ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
olùdámọràn ètò ìṣúná tẹnumọ pàtàkì gbígbé ṣáájú isanpada gbèsè nínú ìṣúná tó dí gágá
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
afowósókowò [um] sábà máa n dábàá yíya [?] ìdá ogún sọtọ nínú owó sọtọ nínú owó oṣù fún àwọn ìlépa owó ìgbà pípẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
ó tiraka láti láti ṣètò ìṣúná rẹ nítorí àìlèṣafojúsùn iṣẹ ìwé kíkọ àtiléṣe rẹ
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
àṣìṣe ìsopọ àpòowó náà fa ìdádúró tó lágbára nínú ṣíṣe àwọn ìbáramu ogun ifowosokowo
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
|
bó ṣe ṣe ìdúnadúrà ẹrọ alágbèélétan tuntun rẹ ìjáyà wọlé fún nípa ìnáwó tí ó pọjù
|
YBUT1F29
|
15-29
|
BU
|
female
|
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 3