en
stringlengths
5
934
yo
stringlengths
4
1.13k
_Location:
_Áíkànnù:
_Previous Tab
_Táàbù Tilẹ̀
_Minimum size:
_Ìwọ̀n tó kéré jù:
_Password:
_Àmì-àṣírí:
Send email to address “%s”
Fi lẹ́tà kọ̀ǹpútà ránṣẹ́ sí àdírẹ̀sì “%s”
Go to the first page
Lọ sí ojú-ìwé àkọ́kọ́
Connect to Server...
Darapọ̀ mọ́ Sáfà...
Go to the previous visited page
Lọ sí Ojú-ìwé tí a bẹ̀ wò tẹ́lẹ̀
_Address:
_Àdírẹ̀sì:
_Name of fish:
_Orúkọ ẹja:
_Page Source
_Orísun Ojú-ìwé
_Total frames in animation:
_Gbogbo àwọn férèmù nínú ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà:
Field _Value
Fálù _Ààyè Wúnrẹ̀n
A list of panel applet IDs. Each ID identifies an individual panel applet. The settings for each of these applets are stored in /apps/panel/applets/$(id).
Àtòjọ àwọn ID ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ń tọ́ka sí ápúlẹ́ẹ̀tì pánẹ́ẹ̀lì.A fi àwọn ààtò fún àwọn ápúlẹ́ẹ̀tì kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/applets/$(id).
Create a new launcher
Ṣẹ̀dá aṣàfilọ́lẹ̀ tuntun
_Log out
_Parí iṣẹ́
This key specifies the filename of the pixmap which will be used for the animation displayed in the fish applet relative to the pixmap directory.
Bọ́tìnì yìí sọ ní pàtó orúkọ-fáìlì pixmap tí a óò lò fún ìṣàfarawé kọ̀ǹpútà tí aṣàfihàn nínú ápúlẹ́ẹ̀tì ẹja tó jọ atọ́nà pixmap.
A simple applet for testing the GNOME panel
Ápúlẹ́ẹ̀tì alábọ̀dé kan fún ìyẹ̀wò pánẹ́ẹ̀lì GNOME-2.0
Go to the last page
Lọ sí ojú-ìwé tó gbẹ̀yìn
"%s" found in configuration database is not a valid value for mouse button modifier
"%s" tí a rí nínú èròjà ìwádìí àtòpọ̀ kìí ṣe fálù tó fẹsẹ̀múlẹ̀ fún aṣàtúntò bọ́tìnì ohun-èlò aṣèkúté
Warning: The command appears to be something actually useful. Since this is a useless applet, you may not want to do this. We strongly advise you against using %s for anything which would make the applet "practical" or useful.
Ìkìlọ̀: Ó jọ wí pé àṣẹ náà máa wúlò. Níwọ̀n ìgbà tí ápúlẹ́ẹ̀tì yìí kò wúlò, o lè má fẹ́ ṣe èyí. A gbà ẹ́ nímọ̀ràn gidi kí o má lo %s fún ohunkóhun tí yóò mú ápúlẹ́ẹ̀tì náà "jẹ́ ṣíṣe" tàbí wúlò.
The fish's name
Orúkọ ẹja náà
_Applications:
_Àwọn Ìṣàmúlò-ètò:
A list of panel IDs. Each ID identifies an individual toplevel panel. The settings for each of these panels are stored in /apps/panel/toplevels/$(id).
Àtòjọ àwọn ID pánẹ́ẹ̀lì. ID kọ̀ọ̀kan ló n tọ́ka sí pánẹ́ẹ̀lì ìpele-òkè kọ̀ọ̀kan. A fi àwọnà̀àtò̀ fún àwọn pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/toplevels/$(id).
Learn more about GNOME
Nípa GNOME
_Orientation:
_Ìṣàlàyé:
Go to the next visited page
Lọ sí ojú-ìwé tókàn tí a óò bẹ̀ wò
The bookmarks from “%s” could not be imported because the file is corrupted or of an unsupported type.
A kò lè gbé àwọn àmì-ìwé tí a gbé láti inú “%s” wọlé nítorí pé fáìlì náà ti bàjẹ́ tàbí kó jẹ̀ irúfẹ́ tí kò ní àtìlẹ́yìn.
You should have received a copy of the GNU General Public License along with the GNOME Web Browser; if not, write to the Free Software Foundation, Inc., 51 Franklin Street, Fifth Floor, Boston, MA 02110-1301 USA
Ó yẹ kí o ti gba ẹ̀dà Ìwé-àṣẹ Gbogbo ti GNU pẹ̀lú Awáròyìn Wẹ́ẹ̀bù GNOME; tí kò bá rí bẹ́ẹ̀ kọ̀wé sí Free Software Foundation, Inc., 59 Temple Place, Suite 330, Boston, MA 02111-1307 USA
Click this button to browse for a file whose name to append to the command string.
Tẹ bọ́tìnì yìí láti wáròyìn fún fáìlì tí a óò ṣàfikún orúkọ rẹ̀ sí fọ́nránàṣẹ.
Games and amusements
Àwọn ayò àti àwọn eré-àṣenọjú
_Speak again
_Sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan si
Choose a file to append to the command...
Yan fáìlì láti ṣàfikún àṣẹ náà...
Some other program is already using the key %s with modifiers %x as a binding
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àtòjọ-ètò mìíràn ló ń ti ń lo bọ́tìnì %s tẹ́lẹ̀ pẹ́lú àwọn aṣàtúntò %x gẹ́gẹ́ bíi aṣẹ̀dá-ìtọ́ka
The currently selected fonts language. Valid values are "ar" (arabic), "x-baltic" (baltic languages), "x-central-euro" (central european languages), "x-cyrillic" (languages written with cyrillic alphabet), "el" (greek), "he" (hebrew), "ja" (japanese), "ko" (korean), "zh-CN" (simplified chinese), "th" (thai), "zh-TW" (traditional chinese), "tr" (turkish), "x-unicode" (other languages), "x-western" (languages written in latin script), "x-tamil" (tamil) and "x-devanagari" (devanagari).
Èdè àwọn ìrísí-lẹ́tà tí a ṣẹ̀ yàn lọ́wọ́lọ́wọ́. Àwọn fálù tó fẹ̀sẹ̀múlẹ̀ ni "ar" (arabic), "x-baltic" (baltic languages), "x-central-euro" (central european languages), "x-cyrillic" (languages written with cyrillic alphabet), "el" (greek), "he" (hebrew), "ja" (japanese), "ko" (korean), "zh-CN" (simplified chinese), "th" (thai), "zh-TW" (traditional chinese), "tr" (turkish), "x-unicode" (other languages), "x-western" (languages written in latin script), "x-tamil" (tamil) and "x-devanagari" (devanagari).
Could not launch application
Kò lè fi àíkànnù lọ́lẹ̀
Download this file?
Ṣàgbéwọlé fáìlì yìí?
All sites
Gbogbo àwọn fáìlì
Epiphany cannot quit
Epiphany kò lè jáde
Go to the previous page
Lọ sí ojú-ìwé tilẹ̀
Import bookmarks from the given file
Gbé àwọn àmì-ìwé wọlé láti inú fáìlì náà
Show “%s”
Fi “%s” hàn
Create new file in the given directory
Ṣẹ̀dá fáìlì tuntun nínú atọ́nà náà
_Pause
_Dúró díẹ̀
If true, buttons will be placed on each side of the panel which may be used to move the panel to edge of the screen, leaving only a button showing.
Tó bá jẹ́ ò̀ótọ́,a óò gbé àwọn bọ́tìnì sí ẹ̀̀̀gbẹ́ pánẹ́ẹ̀lì kọ̀ọ̀kan tí a lè lò láti gbé pánẹ́ẹ̀lìnáà lọ sí igun ojú kọ̀ǹpútà náà. Yóò sì fi bọ́tìnì kan tó ń ṣàfihàn sílẹ̀
Common Name:
Orúkọ Tó Wọ́pọ̀:
Could not connect to server
Kò lè darapọ̀ mọ́ sáfà
Could not execute '%s'
Kò lè mu '%s' ṣiṣẹ́
Click to view your appointments and tasks
Tẹ̀ láti wo àwọn àdéhùn-ìpàdé àti àwọn iṣẹ́ rẹ
_Page address
_Àdírẹ̀sì ojú-ìwé
GNOME includes most of what you see on your computer, including the file manager, web browser, menus, and many applications.
GNOME pẹlúu ọpọ àwọn ohun tí ó yọ lójú kọmpútà, tí ò pẹlú páálí ìwéolùdarí, ìbojúwo ìwunpọ, ètò, àti ọpọlọpọ ìdarí kọmpútà.
(with minor help from George)
(pẹ̀lú ìrànwọ́ kékeré láti ọ̀dọ́ George)
Could not connect to the session manager
Kò lè darapọ̀ mọ́ alábòójútó sáà
GNOME's greatest strength is our strong community. Virtually anyone, with or without coding skills, can contribute to making GNOME better.
Ipa pàtàkì GNOME Jẹ ìgbóra àgbèègbè wa. Ódàbì pé ẹnikẹni tí ó ní ìmọ ojútùú tàbí tí kò ní, lè sapa àti mú GNOME dára si.
Go to next page
Lọ sí ojú-ìwé tókàn
Epiphany can't be used now. Initialization failed.
A kò lè lo Epiphany báyìí. Ìmúbẹ̀rẹ̀ Mozilla kùnà.
Past developers:
Àwọn oníṣẹ́-ọ̀nà tẹ́lẹ̀:
I didn't have to wait too long for confirmation.
Mi ò ní láti dúró pẹ́ fún ìfẹsẹ̀múlẹ̀ rẹ̀.
A section of an economics course textbook that explains the economic principles underlying potential threats to the commons
Apá kan nínú ìwé-lílò-ẹ̀kọ́ abala-ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ìṣúná tí ó ń ṣàlàyé òfin ìpilẹ̀ ìmọ̀-ìṣúná tí ó tọ́ka sí àwọn ohun tí ó ń fa ìfàsẹ́yìn fún àjọṣegbogboènìyàn
I've been on one of these, and I didn't have a helmet, either.
Mo ti wà nínú ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí rí, mi ò sì ní akoto, bákan náà.
The local authorities and the grieving family thanked the brothers and sisters because of the effort they expended to share the Bible’s comforting message.
Àwọn aláṣẹ abúlé náà àti ìdílé tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn arákùnrin àti arábìnrin náà fún gbogbo ìsapá tí wọ́n ṣe kí wọ́n lè wá fi Bíbélì, Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tù wọ́n nínú.
But sir, please I have my baby in the room sleeping
Ẹ jọ̀wọ́ ọmọ mi ń sùn nínú ilé
Just days before the final verdict, while delivering his final statement to the court, Brother Christensen noted: “The truth sooner or later becomes obvious, and it will be the case in this matter.”
Nínú ọ̀rọ̀ àsọkẹ́yìn tó sọ nílé ẹjọ́ ní ọjọ́ díẹ̀ ṣáájú ọjọ́ tí wọ́n dájọ́ rẹ̀, Arákùnrin Christensen sọ pé: “Bópẹ́ bóyá, ohun tó jẹ́ òótọ́ máa hàn kedere, bó sì ṣe máa rí nínú ẹjọ́ yìí náà nìyẹn.”
Another 30 brothers and sisters have been made to sign a document preventing them from leaving their hometowns without obtaining permission from local authorities.
Àwọn ọgbọ̀n (30) míì tún wà lára àwọn ará wa lọ́kùnrin àti lóbìnrin tí wọ́n ti mú kí wọ́n tọwọ́ bọ̀wé pé wọn ò gbọ́dọ̀ jáde nílé wọn láìgba àyè lọ́dọ̀ àwọn aláṣẹ ìlú.
I don't even know your friend
Mi ò tiẹ̀ mọ ọ̀rẹ́ ẹ
Would you tell us about that opportunity and why you refused to sign?
Ṣé ẹ lè sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ fún wa àti ìdí tẹ́ ẹ fi kọ̀ láti buwọ́ lù ú?
In Mexico City and the states of Mexico, Morelos, and Puebla, the 7.1-magnitude earthquake that struck on September 19 displaced 463 brothers and sisters.
Ní Mexico City àti ní Morelos àti Puebla, àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin ọgọ́rùn mẹ́rin ó lé ọgọ́ta àti mẹ́ta [463] ni ìjì líle tó wáyé ní September 19 ba ilé wọn jẹ́.
Russian Court Sentences Brother Alushkin to Six Years in Prison
Ilé Ẹjọ́ Kan ní Rọ́ṣíà Rán Arákùnrin Alushkin Lọ sí Ẹ̀wọ̀n Ọdún Mẹ́fà
“Gianni Infantino will be in Nigeria on Monday for the FIFA Executive Summit which will be a three-day event and this will bring all international media down to Nigeria,” Pinnick said.
"Pinnick fikún ọrọ rẹ̀ pé, Ààrẹ àjọ FIFA, Gianni Infantino yóò gúnlẹ̀ sí Nàìjííríà lọ́jọ́ Ajé (Monday) fún ìpàdé ọlọ́jọ́ mẹ́ta ọ̀hún, bẹ́ẹ̀ sìni yóò mú àwọn akọ̀ròyìn lágbàáyé wá sórílẹ̀-èdè Nàìjííríà,"""
Among these, 1,500 lost their lives.
Ẹ̀mí ẹgbẹ̀rún kan ààbọ̀ (1,500) lára wọn ló lọ sí i.
There are now 60 relief committees, which have primarily been tasked with distributing food to the brothers and sisters.
Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, ọgọ́ta (60) ìgbìmọ̀ tó ń ṣètò ìrànwọ́ ló ń ṣiṣẹ́ kára láti pín oúnjẹ fáwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin.
Twenty six Athletes from Kwara State have been invited to camp in ten different sports ahead of the preparations for the Africa Youth Games, holding in Algiers, Algeria, later in the year.
Eléré sísá mé̩rìndínló̩gbò̩n nípìnínlè̩ Kwara ti kó lọ sípàgó̩ fúngbàáradì de ìdíje oríṣìí eré ìdárayá mé̩wàá tí yóò wáyé ní eré àwọn ò̩dó̩ ilè̩ Adúláwò̩ ní Algiers ni orílè̩ èdè Algeria láìpé̩.
“We quite appreciate the aspirations of Nigerians and the government remains focused and determined to ensure that all the promises regarding the economy and creating more jobs will come through.
Mínísítà tún tẹ̀síwájú pé “A mọ̀ rírì ohun tí àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ń fẹ́, ìjọba kò sì ní káàrẹ́ láti mú gbogbo ìlérí tí ó se sẹ́, páàpáà jùlọ nípa ètò ọrọ̀ ajé àti láti pèsè isẹ́ lọ́pọ̀ janturu.
We are encouraged by the strong faith of our fellow believers, such as Brother Skrynnikov.
Ìgbàgbọ́ tó lágbára táwọn ará wa ní máa ń fún wa níṣìírí bíi ti Arákùnrin Skrynnikov.
In the city of Sangli, located some 378 kilometers (235 mi) southeast of Mumbai, 25 publishers were displaced.
Ní ìlú Sangli, tó wà ní nǹkan bíi 378 kìlómítà sí ìlú Mumbai, àwọn akéde mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ló sá fi ilé wọn sílẹ̀.
(1 Peter 2:17; 5:9) Most of all, we unitedly thank Jehovah, “the God who supplies endurance and comfort.”—Romans 15:5.
(1 Pétérù 2:17; 5:9) Àmọ́ ọpẹ́ wa tó ga jù lọ sọ́dọ̀ Jèhófà, “Ọlọ́run tí ń pèsè ìfaradà àti ìtùnú.”—Róòmù 15:5.
1.What do I want to protect?
1. Kí ni mo fẹ́ fi ààbò bò?
Do I have anything in my house that I cannot replace?
Ǹjẹ́ mo ní nǹkankan nínú ilé tí n kò le è pààrọ̀ọ rẹ̀?
MA: The brothers and sisters really helped me.
MA: Àwọn ará lọ́kùnrin lóbìnrin ràn mí lọ́wọ́ gan-an.
"We are thankful that Jehovah responds to all the prayers in behalf of those in “prison bonds.”—Colossians 4:2, 3."""
"A dúpẹ́ pé Jèhófà ń dáhùn àwọn àdúrà tá a gbà nítorí àwọn tó wa nínú “ìdè ẹ̀wọ̀n.”​—Kólósè 4:​2, 3."""
The Governor said the two projects were of significant importance to both Cross River State and the country at large.
Gómìnà náà sọ pé isẹ́ àkànṣe méjì ní ìjọba òhun tí gùnlé, ní èyí tí ó se pàtàkì sí ìpínlẹ̀ Cross River àti orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.
It extended the term of copyright for every work in the United States—even those already published—for an additional 20 years, so the copyright term equaled the life of the creator plus 70 years.
Ó fa ìkáwọ́ èdè-ìperí àṣẹ-ẹ̀dà gùn láti kan gbogbo iṣẹ́ tí ó ba jẹ́ ti Ìpínlẹ̀ Ìṣọ̀kan ti America—títí kan àwọn tí a ti tẹ̀ jáde tẹ́lẹ̀—pẹ̀lú àfikún ọdún 20 sí ọjọ́ tí a tẹ̀ ẹ́, torí náà èdè-ìperí fi ìgbé ayé oníṣẹ́-ọpọlọ àti àfikún ọdún 70 sí ọgbọọgba.
The Federal Executive Council FEC, has approved over nine hundred million naira for building residential accommodation for the Nigeria Customs Services.
Àjọ orílẹ̀ èdè tì buwọ́lu owó rọ̀gùn-rọ́gún Ọgọ́rùnmẹ́sà án Million Naira láti fi kọ́ ilé tó bójúmu fún àwọn Aṣọ́bodè ilẹ̀ wa.
Global inequality is a wrenching, intensifying problem.
Aìdọ́gba àgbáyé jẹ́ ìṣòro tó ń rún nǹkan, t’ó sì lágbára.
If I hear this thing from anyone else
Tí mo bá gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí lẹ́nu ẹlòmíì
There are some very smart people, smart engineers at Google and Facebook, who are trying to use technology to stop the spread of fake news.
Àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyán kan wà, àwọn onímọ̀-ẹ̀rọ tí wọ́n gbọ́n ní Google àti Facebook, tí wọ́n ń gbìyànjú láti fi ìmọ̀-ẹ̀rọ dá ìròyìn òfegè dúró.
"Her experience reminds us that we should “not give up in doing what is fine, for in due time we will reap if we do not tire out.”—Galatians 6:9."""
"Ìrírí Daphane yìí rán wa létí pé kò yẹ “kí a jáwọ́ nínú ṣíṣe rere, torí tí àkókò bá tó, a máa kórè rẹ̀ tí a ò bá jẹ́ kó rẹ̀ wá.”​—⁠Gálátíà 6:⁠9."""
Guy calm down, it's my wife we're talking about here
Ọ̀gbẹ́ni fara balẹ̀, ìyàwó mi ni ẹni tí à ń sọ yìí
The previous month, fires broke out in Taguig City on the island of Luzon.
Lóṣù kan sáájú àkókò yẹn, iná sọ láwọn ibì kan ní ìlú Taguig City tó wà ní erékùṣù Luzon.
According to the court decision, “the justification of the state of necessity .
Bí ilé ẹjọ́ náà ṣe sọ, “ti pé dókítà rí i pé ìtọ́jú kan pọn dandan .
In January 2019, the museum exhibits at world headquarters were officially made available in American Sign Language (ASL).
Bẹ̀rẹ̀ láti January 2019, ó ti ṣeé ṣe fáwọn tó gbọ́ Èdè Adití ti Amẹ́ríkà (ASL) láti túbọ̀ gbádùn ìbẹ̀wò wọn sí oríléeṣẹ́ wa.
Initial reports have been received from the Central America branch office with the following information. Unfortunately, it has been confirmed that one of our sisters in Mexico City was killed in the quake.
Ìròyìn tá a kọ́kọ́ gbọ́ láti ẹ̀ka ọ́fíìsì Central America rèé: Ó dùn wá gan-an pé ọ̀kan lára àwọn arábìnrin wa ní Mexico City kú sínú ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
Most email providers give you a way of accessing your email using a web browser, such as Firefox or Chrome.
Ọ̀pọ̀ apèsè ímeèlì fún ọ láàyè láti yẹ ímeèlìi wò lórí ìtàkùn aṣàwáríkiri, gẹ́gẹ́ bíi Firefox tàbí Chrome.
--- I promises nonpartisan leadership: Ahmed Lawan.
--- Èmi ò ní yọ ẹnìkankan sílẹ̀ níbi ìsàkoso mi: Ahmed Lawan.
The Supreme Court reversed four lower court rulings against our brothers, and the Administrative Court reversed a fifth decision.
Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ yí ìdájọ́ mẹ́rin táwọn ilé ẹjọ́ kan ti ṣe fáwọn ará wa tẹ́lẹ̀ pa dà, Ilé Ẹjọ́ Ìjọba sì tún yí ẹjọ́ kan pa dà láfikún sí àwọn ẹjọ́ mẹ́rin náà.
"""On September 4, 2019, during the trial of six Jehovah’s Witnesses in Saratov, a well-known religious scholar and state advisor to the Russian Federation, Sergey Igorevich Ivanenko, was invited to testify under oath on behalf of Jehovah’s Witnesses."
"""Ní September 4, 2019, nígbà tí wọ́n ń gbẹ́jọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mẹ́fà ní ìlú Saratov, wọ́n ní kí onímọ̀ nípa ẹ̀sìn táwọn èèyàn mọ̀ bí ẹní mowó àti olùdámọ̀ràn fún ìjọba Orílẹ̀-Èdè Rọ́ṣíà, Sergey Igorevich Ivanenko, wá sọ ohun tó mọ̀ nípa àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà níwájú ilé ẹjọ́."
But it will be possible in the future, and I am looking forward to it.”
Àmọ́, ó máa ṣeéṣe lọ́jọ́ iwájú, mo sì ń wọ̀nà fún un.”
Mr. Uduak charged hotel owners to improve the technological watch of their hotels by embracing electronic surveillance, such as CCTV. He also implored them to be alert and work with the police to bring them to book, by reporting them to the police, whenever there is any sign that identifies them as a cult group.
Uduak rọ gbogbo àwọn tó ní ilé ìtura láti máa lo ẹ̀rọ ònmọ̀ CCTV kí wọ́n si ma fi tó àwọn ọlọ́ọ̀pá létí nígbàkigbà tí wọ́n bá kẹ́ẹ́fín wọn.
"""Brother Arkadya Akopyan will have his final day in court on December 21, 2018."
"""December 21, 2018 ni Arákùnrin Arkadya Akopyan, máa fara hàn kẹ́yìn nílé ẹjọ́."
"We pray that our brothers and sisters in the Philippines will continue to trust in Jehovah, “our refuge and strength.”—Psalm 46:1-3."""
"Àdúrà wa ni pé kí ìgbàgbọ́ àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa lórílẹ̀-èdè Philippines lágbára sí i, kó sì túbọ̀ dá wọn lójú pé Jèhófà ni Ọlọ́run “ààbò wa àti okun wa.”​—Sáàmù 46:​1-3."""