Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
en
stringlengths
5
934
yo
stringlengths
4
1.13k
_Location:
_ÁíkaΜ€nnuΜ€:
_Previous Tab
_TáaΜ€buΜ€ TilαΊΉΜ€
_Minimum size:
_IΜ€wọ̀n tó kéré juΜ€:
_Password:
_AΜ€miΜ€-aΜ€αΉ£írí:
Send email to address β€œ%s”
Fi lẹ́taΜ€ kọ̀nΜ€pútaΜ€ ránṣẹ́ sí aΜ€dírαΊΉΜ€siΜ€ β€œ%s”
Go to the first page
Lọ sí ojú-iΜ€wé aΜ€kọ́kọ́
Connect to Server...
Darapọ̀ mọ́ SáfaΜ€...
Go to the previous visited page
Lọ sí Ojú-iΜ€wé tí a bαΊΉΜ€ woΜ€ tẹ́lαΊΉΜ€
_Address:
_AΜ€dírαΊΉΜ€siΜ€:
_Name of fish:
_Orúkọ ẹja:
_Page Source
_Orísun Ojú-iΜ€wé
_Total frames in animation:
_Gbogbo aΜ€wọn féreΜ€muΜ€ nínú iΜ€αΉ£aΜ€farawé kọ̀nΜ€pútaΜ€:
Field _Value
FáluΜ€ _AΜ€aΜ€yeΜ€ WúnrαΊΉΜ€n
A list of panel applet IDs. Each ID identifies an individual panel applet. The settings for each of these applets are stored in /apps/panel/applets/$(id).
AΜ€toΜ€jọ aΜ€wọn ID ápúlẹ́ẹ̀tiΜ€ pánẹ́ẹ̀liΜ€. ID kọ̀ọ̀kan ń tọ́ka sí ápúlẹ́ẹ̀tiΜ€ pánẹ́ẹ̀liΜ€.A fi aΜ€wọn aΜ€aΜ€toΜ€ fún aΜ€wọn ápúlẹ́ẹ̀tiΜ€ kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/applets/$(id).
Create a new launcher
αΉ’αΊΉΜ€dá aαΉ£aΜ€filọ́lαΊΉΜ€ tuntun
_Log out
_Parí iṣẹ́
This key specifies the filename of the pixmap which will be used for the animation displayed in the fish applet relative to the pixmap directory.
Bọ́tiΜ€niΜ€ yiΜ€í sọ ní paΜ€tó orúkọ-fáiΜ€liΜ€ pixmap tí a óoΜ€ loΜ€ fún iΜ€αΉ£aΜ€farawé kọ̀nΜ€pútaΜ€ tí aαΉ£aΜ€fihaΜ€n nínú ápúlẹ́ẹ̀tiΜ€ αΊΉja tó jọ atọ́naΜ€ pixmap.
A simple applet for testing the GNOME panel
Ápúlẹ́ẹ̀tiΜ€ alábọ̀dé kan fún iΜ€yαΊΉΜ€woΜ€ pánẹ́ẹ̀liΜ€ GNOME-2.0
Go to the last page
Lọ sí ojú-iΜ€wé tó gbαΊΉΜ€yiΜ€n
"%s" found in configuration database is not a valid value for mouse button modifier
"%s" tí a rí nínú eΜ€roΜ€jaΜ€ iΜ€wádiΜ€í aΜ€toΜ€pọ̀ kiΜ€í αΉ£e fáluΜ€ tó fαΊΉsαΊΉΜ€múlαΊΉΜ€ fún aαΉ£aΜ€túntoΜ€ bọ́tiΜ€niΜ€ ohun-eΜ€loΜ€ aαΉ£eΜ€kúté
Warning: The command appears to be something actually useful. Since this is a useless applet, you may not want to do this. We strongly advise you against using %s for anything which would make the applet "practical" or useful.
IΜ€kiΜ€lọ̀: Ó jọ wí pé aΜ€αΉ£αΊΉ náaΜ€ máa wúloΜ€. Níwọ̀n iΜ€gbaΜ€ tí ápúlẹ́ẹ̀tiΜ€ yiΜ€í koΜ€ wúloΜ€, o leΜ€ má fẹ́ αΉ£e eΜ€yí. A gbaΜ€ ẹ́ nímọ̀raΜ€n gidi kí o má lo %s fún ohunkóhun tí yóoΜ€ mú ápúlẹ́ẹ̀tiΜ€ náaΜ€ "jẹ́ αΉ£íṣe" taΜ€bí wúloΜ€.
The fish's name
Orúkọ αΊΉja náaΜ€
_Applications:
_AΜ€wọn IΜ€αΉ£aΜ€múloΜ€-eΜ€toΜ€:
A list of panel IDs. Each ID identifies an individual toplevel panel. The settings for each of these panels are stored in /apps/panel/toplevels/$(id).
AΜ€toΜ€jọ aΜ€wọn ID pánẹ́ẹ̀liΜ€. ID kọ̀ọ̀kan ló n tọ́ka sí pánẹ́ẹ̀liΜ€ iΜ€pele-oΜ€keΜ€ kọ̀ọ̀kan. A fi aΜ€wọnaΜ€Μ€aΜ€toΜ€Μ€ fún aΜ€wọn pánẹ́ẹ̀liΜ€ kọ̀ọ̀kan pamọ́ sínú /apps/panel/toplevels/$(id).
Learn more about GNOME
NΓ­pa GNOME
_Orientation:
_IΜ€αΉ£aΜ€laΜ€yé:
Go to the next visited page
Lọ sí ojú-iΜ€wé tókaΜ€n tí a óoΜ€ bαΊΉΜ€ woΜ€
The bookmarks from β€œ%s” could not be imported because the file is corrupted or of an unsupported type.
A koΜ€ leΜ€ gbé aΜ€wọn aΜ€miΜ€-iΜ€wé tí a gbé láti inú β€œ%s” wọlé nítorí pé fáiΜ€liΜ€ náaΜ€ ti baΜ€jẹ́ taΜ€bí kó jαΊΉΜ€ irúfẹ́ tí koΜ€ ní aΜ€tiΜ€lẹ́yiΜ€n.
You should have received a copy of the GNU General Public License along with the GNOME Web Browser; if not, write to the Free Software Foundation, Inc., 51 Franklin Street, Fifth Floor, Boston, MA 02110-1301 USA
Ó yαΊΉ kí o ti gba αΊΉΜ€daΜ€ IΜ€wé-aΜ€αΉ£αΊΉ Gbogbo ti GNU pαΊΉΜ€lú AwároΜ€yiΜ€n Wẹ́ẹ̀buΜ€ GNOME; tí koΜ€ bá rí bẹ́ẹ̀ kọ̀wé sí Free Software Foundation, Inc., 59 Temple Place, Suite 330, Boston, MA 02111-1307 USA
Click this button to browse for a file whose name to append to the command string.
TαΊΉ bọ́tiΜ€niΜ€ yiΜ€í láti wároΜ€yiΜ€n fún fáiΜ€liΜ€ tí a óoΜ€ αΉ£aΜ€fikún orúkọ rαΊΉΜ€ sí fọ́nránaΜ€αΉ£αΊΉ.
Games and amusements
AΜ€wọn ayoΜ€ aΜ€ti aΜ€wọn eré-aΜ€αΉ£enọjú
_Speak again
_Sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan si
Choose a file to append to the command...
Yan fáiΜ€liΜ€ láti αΉ£aΜ€fikún aΜ€αΉ£αΊΉ náaΜ€...
Some other program is already using the key %s with modifiers %x as a binding
α»ŒΜ€pọ̀lọpọ̀ aΜ€toΜ€jọ-eΜ€toΜ€ miΜ€íraΜ€n ló ń ti ń lo bọ́tiΜ€niΜ€ %s tẹ́lαΊΉΜ€ pẹ́lú aΜ€wọn aαΉ£aΜ€túntoΜ€ %x gẹ́gẹ́ bíi aαΉ£αΊΉΜ€dá-iΜ€tọ́ka
The currently selected fonts language. Valid values are "ar" (arabic), "x-baltic" (baltic languages), "x-central-euro" (central european languages), "x-cyrillic" (languages written with cyrillic alphabet), "el" (greek), "he" (hebrew), "ja" (japanese), "ko" (korean), "zh-CN" (simplified chinese), "th" (thai), "zh-TW" (traditional chinese), "tr" (turkish), "x-unicode" (other languages), "x-western" (languages written in latin script), "x-tamil" (tamil) and "x-devanagari" (devanagari).
EΜ€deΜ€ aΜ€wọn iΜ€rísí-lẹ́taΜ€ tí a αΉ£αΊΉΜ€ yaΜ€n lọ́wọ́lọ́wọ́. AΜ€wọn fáluΜ€ tó fαΊΉΜ€sαΊΉΜ€múlαΊΉΜ€ ni "ar" (arabic), "x-baltic" (baltic languages), "x-central-euro" (central european languages), "x-cyrillic" (languages written with cyrillic alphabet), "el" (greek), "he" (hebrew), "ja" (japanese), "ko" (korean), "zh-CN" (simplified chinese), "th" (thai), "zh-TW" (traditional chinese), "tr" (turkish), "x-unicode" (other languages), "x-western" (languages written in latin script), "x-tamil" (tamil) and "x-devanagari" (devanagari).
Could not launch application
KoΜ€ leΜ€ fi aΜ€íkaΜ€nnuΜ€ lọ́lαΊΉΜ€
Download this file?
αΉ’aΜ€gbéwọlé fáiΜ€liΜ€ yiΜ€í?
All sites
Gbogbo aΜ€wọn fáiΜ€liΜ€
Epiphany cannot quit
Epiphany koΜ€ leΜ€ jáde
Go to the previous page
Lọ sí ojú-iΜ€wé tilαΊΉΜ€
Import bookmarks from the given file
Gbé aΜ€wọn aΜ€miΜ€-iΜ€wé wọlé láti inú fáiΜ€liΜ€ náaΜ€
Show β€œ%s”
Fi β€œ%s” haΜ€n
Create new file in the given directory
αΉ’αΊΉΜ€dá fáiΜ€liΜ€ tuntun nínú atọ́naΜ€ náaΜ€
_Pause
_Dúró díẹ̀
If true, buttons will be placed on each side of the panel which may be used to move the panel to edge of the screen, leaving only a button showing.
Tó bá jẹ́ oΜ€Μ€ótọ́,a óoΜ€ gbé aΜ€wọn bọ́tiΜ€niΜ€ sí αΊΉΜ€Μ€Μ€gbẹ́ pánẹ́ẹ̀liΜ€ kọ̀ọ̀kan tí a leΜ€ loΜ€ láti gbé pánẹ́ẹ̀liΜ€náaΜ€ lọ sí igun ojú kọ̀nΜ€pútaΜ€ náaΜ€. YóoΜ€ siΜ€ fi bọ́tiΜ€niΜ€ kan tó ń αΉ£aΜ€fihaΜ€n sílαΊΉΜ€
Common Name:
Orúkọ Tó Wọ́pọ̀:
Could not connect to server
KoΜ€ leΜ€ darapọ̀ mọ́ sáfaΜ€
Could not execute '%s'
KoΜ€ leΜ€ mu '%s' αΉ£iṣẹ́
Click to view your appointments and tasks
TαΊΉΜ€ láti wo aΜ€wọn aΜ€déhuΜ€n-iΜ€paΜ€dé aΜ€ti aΜ€wọn iṣẹ́ rαΊΉ
_Page address
_AΜ€dírαΊΉΜ€siΜ€ ojú-iΜ€wé
GNOME includes most of what you see on your computer, including the file manager, web browser, menus, and many applications.
GNOME pẹlúu ọpọ àwọn ohun tí ó yọ lójú kọmpútà, tí ò pẹlú pÑÑlí ìwéolùdarí, ìbojúwo ìwunpọ, ètò, àti ọpọlọpọ ìdarí kọmpútà.
(with minor help from George)
(pαΊΉΜ€lú iΜ€raΜ€nwọ́ kékeré láti ọ̀dọ́ George)
Could not connect to the session manager
KoΜ€ leΜ€ darapọ̀ mọ́ aláboΜ€ójútó sáaΜ€
GNOME's greatest strength is our strong community. Virtually anyone, with or without coding skills, can contribute to making GNOME better.
Ipa pΓ tΓ kΓ¬ GNOME JαΊΉ Γ¬gbΓ³ra Γ gbèègbΓ¨ wa. Γ“dΓ bΓ¬ pΓ© αΊΉnikαΊΉni tΓ­ Γ³ nΓ­ Γ¬mọ ojΓΊtΓΉΓΊ tΓ bΓ­ tΓ­ kΓ² nΓ­, lΓ¨ sapa Γ ti mΓΊ GNOME dΓ‘ra si.
Go to next page
Lọ sí ojú-iΜ€wé tókaΜ€n
Epiphany can't be used now. Initialization failed.
A koΜ€ leΜ€ lo Epiphany báyiΜ€í. IΜ€múbαΊΉΜ€rαΊΉΜ€ Mozilla kuΜ€naΜ€.
Past developers:
AΜ€wọn oníṣẹ́-ọ̀naΜ€ tẹ́lαΊΉΜ€:
I didn't have to wait too long for confirmation.
Mi Γ² nΓ­ lΓ‘ti dΓΊrΓ³ pẹ́ fΓΊn Γ¬fαΊΉsαΊΉΜ€mΓΊlαΊΉΜ€ rαΊΉΜ€.
A section of an economics course textbook that explains the economic principles underlying potential threats to the commons
ApΓ‘ kan nΓ­nΓΊ Γ¬wΓ©-lΓ­lΓ²-αΊΉΜ€kọ́ abala-αΊΉΜ€kọ́ Γ¬mọ̀-Γ¬αΉ£ΓΊnΓ‘ tΓ­ Γ³ Ε„ αΉ£Γ lΓ yΓ© Γ²fin Γ¬pilαΊΉΜ€ Γ¬mọ̀-Γ¬αΉ£ΓΊnΓ‘ tΓ­ Γ³ tọ́ka sΓ­ Γ wọn ohun tΓ­ Γ³ Ε„ fa Γ¬fΓ sẹ́yΓ¬n fΓΊn Γ jọṣegbogboΓ¨nΓ¬yΓ n
I've been on one of these, and I didn't have a helmet, either.
Mo ti wΓ  nΓ­nΓΊ ọ̀kan nΓ­nΓΊ Γ wọn wọ̀nyΓ­ rΓ­, mi Γ² sΓ¬ nΓ­ akoto, bΓ‘kan nÑà.
The local authorities and the grieving family thanked the brothers and sisters because of the effort they expended to share the Bible’s comforting message.
Γ€wọn alΓ‘αΉ£αΊΉ abΓΊlΓ© nÑà Γ ti Γ¬dΓ­lΓ© tΓ­ ọ̀fọ̀ αΉ£αΊΉΜ€ dΓΊpẹ́ lọ́wọ́ Γ wọn arΓ‘kΓΉnrin Γ ti arΓ‘bΓ¬nrin nÑà fΓΊn gbogbo Γ¬sapΓ‘ tΓ­ wọ́n αΉ£e kΓ­ wọ́n lΓ¨ wΓ‘ fi BΓ­bΓ©lΓ¬, α»ŒΜ€rọ̀ Ọlọ́run tΓΉ wọ́n nΓ­nΓΊ.
But sir, please I have my baby in the room sleeping
αΊΈ jọ̀wọ́ ọmọ mi Ε„ sΓΉn nΓ­nΓΊ ilΓ©
Just days before the final verdict, while delivering his final statement to the court, Brother Christensen noted: β€œThe truth sooner or later becomes obvious, and it will be the case in this matter.”
NΓ­nΓΊ ọ̀rọ̀ Γ sọkẹ́yΓ¬n tΓ³ sọ nΓ­lΓ© αΊΉjọ́ nΓ­ ọjọ́ dΓ­αΊΉΜ€ ṣÑÑjΓΊ ọjọ́ tΓ­ wọ́n dΓ‘jọ́ rαΊΉΜ€, ArΓ‘kΓΉnrin Christensen sọ pΓ©: β€œBΓ³pẹ́ bΓ³yΓ‘, ohun tΓ³ jẹ́ Γ²Γ³tọ́ mΓ‘a hΓ n kedere, bΓ³ sΓ¬ αΉ£e mΓ‘a rΓ­ nΓ­nΓΊ αΊΉjọ́ yìí nÑà nΓ¬yαΊΉn.”
Another 30 brothers and sisters have been made to sign a document preventing them from leaving their hometowns without obtaining permission from local authorities.
Γ€wọn ọgbọ̀n (30) mΓ­Γ¬ tΓΊn wΓ  lΓ‘ra Γ wọn arΓ‘ wa lọ́kΓΉnrin Γ ti lΓ³bΓ¬nrin tΓ­ wọ́n ti mΓΊ kΓ­ wọ́n tọwọ́ bọ̀wΓ© pΓ© wọn Γ² gbọ́dọ̀ jΓ‘de nΓ­lΓ© wọn lÑìgba Γ yΓ¨ lọ́dọ̀ Γ wọn alΓ‘αΉ£αΊΉ Γ¬lΓΊ.
I don't even know your friend
Mi Γ² tiαΊΉΜ€ mọ ọ̀rẹ́ αΊΉ
Would you tell us about that opportunity and why you refused to sign?
αΉ’Γ© αΊΉ lΓ¨ sọ ohun tΓ³ αΉ£αΊΉlαΊΉΜ€ fΓΊn wa Γ ti Γ¬dΓ­ tẹ́ αΊΉ fi kọ̀ lΓ‘ti buwọ́ lΓΉ ΓΊ?
In Mexico City and the states of Mexico, Morelos, and Puebla, the 7.1-magnitude earthquake that struck on September 19 displaced 463 brothers and sisters.
Ní Mexico City àti ní Morelos àti Puebla, àwọn arÑkùnrin àtàwọn arÑbìnrin ọgọ́rùn mẹ́rin ó lé ọgọ́ta àti mẹ́ta [463] ni ìjì líle tó wÑyé ní September 19 ba ilé wọn jẹ́.
Russian Court Sentences BrotherΒ Alushkin to Six Years in Prison
IlΓ© αΊΈjọ́ Kan nΓ­ Rọ́ṣíà RΓ‘n ArΓ‘kΓΉnrin Alushkin Lọ sΓ­ αΊΈΜ€wọ̀n ỌdΓΊn Mẹ́fΓ 
β€œGianni Infantino will be in Nigeria on Monday for the FIFA Executive Summit which will be a three-day event and this will bring all international media down to Nigeria,” Pinnick said.
"Pinnick fikΓΊn ọrọ rαΊΉΜ€ pΓ©, ÀàrαΊΉ Γ jọ FIFA, Gianni Infantino yΓ³Γ² gΓΊnlαΊΉΜ€ sΓ­ NΓ Γ¬jΓ­Γ­rΓ­Γ  lọ́jọ́ AjΓ© (Monday) fΓΊn Γ¬pΓ dΓ© ọlọ́jọ́ mẹ́ta ọ̀hΓΊn, bẹ́ẹ̀ sΓ¬ni yΓ³Γ² mΓΊ Γ wọn akọ̀rΓ²yΓ¬n lΓ‘gbΓ Γ‘yΓ© wΓ‘ sΓ³rΓ­lαΊΉΜ€-Γ¨dΓ¨ NΓ Γ¬jΓ­Γ­rΓ­Γ ,"""
Among these, 1,500 lost their lives.
αΊΈΜ€mΓ­ αΊΉgbαΊΉΜ€rΓΊn kan Γ Γ bọ̀ (1,500) lΓ‘ra wọn lΓ³ lọ sΓ­ i.
There are now 60 relief committees, which have primarily been tasked with distributing food to the brothers and sisters.
Lọ́wọ́lọ́wọ́ bΓ‘yìí, ọgọ́ta (60) Γ¬gbΓ¬mọ̀ tΓ³ Ε„ αΉ£Γ¨tΓ² Γ¬rΓ nwọ́ lΓ³ Ε„ αΉ£iṣẹ́ kΓ‘ra lΓ‘ti pΓ­n oΓΊnjαΊΉ fΓ‘wọn arΓ‘ lọ́kΓΉnrin Γ ti lΓ³bΓ¬nrin.
Twenty six Athletes from Kwara State have been invited to camp in ten different sports ahead of the preparations for the Africa Youth Games, holding in Algiers, Algeria, later in the year.
Eléré sísÑ mé̩rìndínló̩gbò̩n nípìnínlè̩ Kwara ti kó lọ sípàgó̩ fúngbàÑradì de ìdíje oríṣìí eré ìdÑrayÑ mé̩wàÑ tí yóò wÑyé ní eré àwọn ò̩dó̩ ilè̩ AdúlÑwò̩ ní Algiers ni orílè̩ èdè Algeria lÑìpé̩.
β€œWe quite appreciate the aspirations of Nigerians and the government remains focused and determined to ensure that all the promises regarding the economy and creating more jobs will come through.
MΓ­nΓ­sΓ­tΓ  tΓΊn tαΊΉΜ€sΓ­wΓ‘jΓΊ pΓ© β€œA mọ̀ rΓ­rΓ¬ ohun tΓ­ Γ wọn ọmọ orΓ­lαΊΉΜ€ Γ¨dΓ¨ NΓ Γ­jΓ­rΓ­Γ  Ε„ fẹ́, Γ¬jọba kΓ² sΓ¬ nΓ­ kÑàrẹ́ lΓ‘ti mΓΊ gbogbo Γ¬lΓ©rΓ­ tΓ­ Γ³ se sẹ́, pÑàpÑà jΓΉlọ nΓ­pa Γ¨tΓ² ọrọ̀ ajΓ© Γ ti lΓ‘ti pΓ¨sΓ¨ isẹ́ lọ́pọ̀ janturu.
We are encouraged by the strong faith of our fellow believers, such as Brother Skrynnikov.
ÌgbΓ gbọ́ tΓ³ lΓ‘gbΓ‘ra tΓ‘wọn arΓ‘ wa nΓ­ mΓ‘a Ε„ fΓΊn wa níṣìírΓ­ bΓ­i ti ArΓ‘kΓΉnrin Skrynnikov.
In the city of Sangli, located some 378 kilometers (235 mi) southeast of Mumbai, 25 publishers were displaced.
NΓ­ Γ¬lΓΊ Sangli, tΓ³ wΓ  nΓ­ nΗΉkan bΓ­i 378 kΓ¬lΓ³mΓ­tΓ  sΓ­ Γ¬lΓΊ Mumbai, Γ wọn akΓ©de mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) lΓ³ sΓ‘ fi ilΓ© wọn sΓ­lαΊΉΜ€.
(1 Peter 2:17; 5:9) Most of all, we unitedly thank Jehovah, β€œthe God who supplies endurance and comfort.”—Romans 15:5.
(1 PΓ©tΓ©rΓΉ 2:17; 5:9) Γ€mọ́ ọpẹ́ wa tΓ³ ga jΓΉ lọ sọ́dọ̀ JΓ¨hΓ³fΓ , β€œα»Œlọ́run tΓ­ Ε„ pΓ¨sΓ¨ Γ¬faradΓ  Γ ti Γ¬tΓΉnΓΊ.”—RΓ³Γ²mΓΉ 15:5.
1.What do I want to protect?
1. Kí ni mo fẹ́ fi ààbò bò?
Do I have anything in my house that I cannot replace?
ΗΈjẹ́ mo nΓ­ nΗΉkankan nΓ­nΓΊ ilΓ© tΓ­ n kΓ² le Γ¨ pΓ Γ rọ̀ọ rαΊΉΜ€?
MA: The brothers and sisters really helped me.
MA: Γ€wọn arΓ‘ lọ́kΓΉnrin lΓ³bΓ¬nrin rΓ n mΓ­ lọ́wọ́ gan-an.
"We are thankful that Jehovah responds to all the prayers in behalf of those in β€œprison bonds.”—Colossians 4:2, 3."""
"A dΓΊpẹ́ pΓ© JΓ¨hΓ³fΓ  Ε„ dΓ‘hΓΉn Γ wọn Γ dΓΊrΓ  tΓ‘ a gbΓ  nΓ­torΓ­ Γ wọn tΓ³ wa nΓ­nΓΊ β€œΓ¬dΓ¨ αΊΉΜ€wọ̀n.”​—KΓ³lΓ³sΓ¨ 4:​2, 3."""
The Governor said the two projects were of significant importance to both Cross River State and the country at large.
GΓ³mΓ¬nΓ  nÑà sọ pΓ© isẹ́ Γ kΓ nαΉ£e mΓ©jΓ¬ nΓ­ Γ¬jọba Γ²hun tΓ­ gΓΉnlΓ©, nΓ­ Γ¨yΓ­ tΓ­ Γ³ se pΓ tΓ kΓ¬ sΓ­ Γ¬pΓ­nlαΊΉΜ€ Cross River Γ ti orΓ­lαΊΉΜ€ Γ¨dΓ¨ NΓ Γ­jΓ­rΓ­Γ .
It extended the term of copyright for every work in the United Statesβ€”even those already publishedβ€”for an additional 20 years, so the copyright term equaled the life of the creator plus 70 years.
Γ“ fa Γ¬kΓ‘wọ́ Γ¨dΓ¨-Γ¬perΓ­ Γ αΉ£αΊΉ-αΊΉΜ€dΓ  gΓΉn lΓ‘ti kan gbogbo iṣẹ́ tΓ­ Γ³ ba jẹ́ ti ÌpΓ­nlαΊΉΜ€ ΓŒαΉ£α»Μ€kan ti Americaβ€”tΓ­tΓ­ kan Γ wọn tΓ­ a ti tαΊΉΜ€ jΓ‘de tẹ́lαΊΉΜ€β€”pαΊΉΜ€lΓΊ Γ fikΓΊn ọdΓΊn 20 sΓ­ ọjọ́ tΓ­ a tαΊΉΜ€ ẹ́, torΓ­ nÑà Γ¨dΓ¨-Γ¬perΓ­ fi Γ¬gbΓ© ayΓ© oníṣẹ́-ọpọlọ Γ ti Γ fikΓΊn ọdΓΊn 70 sΓ­ ọgbọọgba.
The Federal Executive Council FEC, has approved over nine hundred million naira for building residential accommodation for the Nigeria Customs Services.
Γ€jọ orΓ­lαΊΉΜ€ Γ¨dΓ¨ tΓ¬ buwọ́lu owΓ³ rọ̀gΓΉn-rọ́gΓΊn Ọgọ́rΓΉnmẹ́sΓ  Γ‘n Million Naira lΓ‘ti fi kọ́ ilΓ© tΓ³ bΓ³jΓΊmu fΓΊn Γ wọn Aṣọ́bodΓ¨ ilαΊΉΜ€ wa.
Global inequality is a wrenching, intensifying problem.
AΓ¬dọ́gba Γ gbΓ‘yΓ© jẹ́ Γ¬αΉ£Γ²ro tΓ³ Ε„ rΓΊn nΗΉkan, t’ó sΓ¬ lΓ‘gbΓ‘ra.
If I hear this thing from anyone else
TΓ­ mo bΓ‘ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí lẹ́nu αΊΉlΓ²mΓ­Γ¬
There are some very smart people, smart engineers at Google and Facebook, who are trying to use technology to stop the spread of fake news.
Γ€wọn ọlọ́gbọ́n Γ¨nΓ¬yΓ‘n kan wΓ , Γ wọn onΓ­mọ̀-αΊΉΜ€rọ tΓ­ wọ́n gbọ́n nΓ­ Google Γ ti Facebook, tΓ­ wọ́n Ε„ gbΓ¬yΓ njΓΊ lΓ‘ti fi Γ¬mọ̀-αΊΉΜ€rọ dΓ‘ Γ¬rΓ²yΓ¬n Γ²fegΓ¨ dΓΊrΓ³.
"Her experience reminds us that we should β€œnot give up in doing what is fine, for in due time we will reap if we do not tire out.”—Galatians 6:9."""
"ÌrΓ­rΓ­ Daphane yìí rΓ‘n wa lΓ©tΓ­ pΓ© kΓ² yαΊΉ β€œkΓ­ a jΓ‘wọ́ nΓ­nΓΊ αΉ£Γ­αΉ£e rere, torΓ­ tΓ­ Γ kΓ³kΓ² bΓ‘ tΓ³, a mΓ‘a kΓ³rΓ¨ rαΊΉΜ€ tΓ­ a Γ² bΓ‘ jẹ́ kΓ³ rαΊΉΜ€ wΓ‘.”​—⁠GΓ‘lΓ‘tΓ­Γ  6:⁠9."""
Guy calm down, it's my wife we're talking about here
α»ŒΜ€gbẹ́ni fara balαΊΉΜ€, Γ¬yΓ wΓ³ mi ni αΊΉni tΓ­ Γ  Ε„ sọ yìí
The previous month, fires broke out in Taguig City on the island of Luzon.
Lóṣù kan sÑÑjú àkókò yẹn, inÑ sọ lÑwọn ibì kan ní ìlú Taguig City tó wà ní erékùṣù Luzon.
According to the court decision, β€œthe justification of the state of necessity .
BΓ­ ilΓ© αΊΉjọ́ nÑà αΉ£e sọ, β€œti pΓ© dΓ³kΓ­tΓ  rΓ­ i pΓ© Γ¬tọ́jΓΊ kan pọn dandan .
In January 2019, the museum exhibits at world headquarters were officially made available in American Sign Language (ASL).
BαΊΉΜ€rαΊΉΜ€ lΓ‘ti January 2019, Γ³ ti αΉ£eΓ© αΉ£e fΓ‘wọn tΓ³ gbọ́ ÈdΓ¨ AditΓ­ ti Amẹ́rΓ­kΓ  (ASL) lΓ‘ti tΓΊbọ̀ gbΓ‘dΓΉn Γ¬bαΊΉΜ€wΓ² wọn sΓ­ orΓ­lΓ©eṣẹ́ wa.
Initial reports have been received from the Central America branch office with the following information. Unfortunately, it has been confirmed that one of our sisters in Mexico City was killed in the quake.
ÌrΓ²yΓ¬n tΓ‘ a kọ́kọ́ gbọ́ lΓ‘ti αΊΉΜ€ka ọ́fΓ­Γ¬sΓ¬ Central America rèé: Γ“ dΓΉn wΓ‘ gan-an pΓ© ọ̀kan lΓ‘ra Γ wọn arΓ‘bΓ¬nrin wa nΓ­ Mexico City kΓΊ sΓ­nΓΊ Γ¬αΉ£αΊΉΜ€lαΊΉΜ€ nÑà.
Most email providers give you a way of accessing your email using a web browser, such as Firefox or Chrome.
α»ŒΜ€pọ̀ apΓ¨sΓ¨ Γ­meΓ¨lΓ¬ fΓΊn ọ lÑàyΓ¨ lΓ‘ti yαΊΉ Γ­meΓ¨lΓ¬i wΓ² lΓ³rΓ­ Γ¬tΓ kΓΉn aαΉ£Γ wΓ‘rΓ­kiri, gẹ́gẹ́ bΓ­i Firefox tΓ bΓ­ Chrome.
--- I promises nonpartisan leadership: Ahmed Lawan.
--- Èmi Γ² nΓ­ yọ αΊΉnΓ¬kankan sΓ­lαΊΉΜ€ nΓ­bi Γ¬sΓ koso mi: Ahmed Lawan.
The Supreme Court reversed four lower court rulings against our brothers, and the Administrative Court reversed a fifth decision.
IlΓ© αΊΈjọ́ GΓ­ga JΓΉ Lọ yΓ­ Γ¬dΓ‘jọ́ mẹ́rin tΓ‘wọn ilΓ© αΊΉjọ́ kan ti αΉ£e fΓ‘wọn arΓ‘ wa tẹ́lαΊΉΜ€ pa dΓ , IlΓ© αΊΈjọ́ Ìjọba sΓ¬ tΓΊn yΓ­ αΊΉjọ́ kan pa dΓ  lΓ‘fikΓΊn sΓ­ Γ wọn αΊΉjọ́ mẹ́rin nÑà.
"""On September 4, 2019, during the trial of six Jehovah’s Witnesses in Saratov, a well-known religious scholar and state advisor to the Russian Federation, Sergey Igorevich Ivanenko, was invited to testify under oath on behalf of Jehovah’s Witnesses."
"""NΓ­ September 4, 2019, nΓ­gbΓ  tΓ­ wọ́n Ε„ gbẹ́jọ́ Γ wọn αΊΈlẹ́rìí JΓ¨hΓ³fΓ  mẹ́fΓ  nΓ­ Γ¬lΓΊ Saratov, wọ́n nΓ­ kΓ­ onΓ­mọ̀ nΓ­pa αΊΉΜ€sΓ¬n tΓ‘wọn èèyΓ n mọ̀ bΓ­ αΊΉnΓ­ mowΓ³ Γ ti olΓΉdΓ‘mọ̀rΓ n fΓΊn Γ¬jọba OrΓ­lαΊΉΜ€-ÈdΓ¨ Rọ́ṣíà, Sergey Igorevich Ivanenko, wΓ‘ sọ ohun tΓ³ mọ̀ nΓ­pa Γ wọn αΊΈlẹ́rìí JΓ¨hΓ³fΓ  nΓ­wΓ‘jΓΊ ilΓ© αΊΉjọ́."
But it will be possible in the future, and I am looking forward to it.”
Γ€mọ́, Γ³ mΓ‘a αΉ£eΓ©αΉ£e lọ́jọ́ iwΓ‘jΓΊ, mo sΓ¬ Ε„ wọ̀nΓ  fΓΊn un.”
Mr. Uduak charged hotel owners to improve the technological watch of their hotels by embracing electronic surveillance, such as CCTV. He also implored them to be alert and work with the police to bring them to book, by reporting them to the police, whenever there is any sign that identifies them as a cult group.
Uduak rọ gbogbo Γ wọn tΓ³ nΓ­ ilΓ© Γ¬tura lΓ‘ti mΓ‘a lo αΊΉΜ€rọ Γ²nmọ̀ CCTV kΓ­ wọ́n si ma fi tΓ³ Γ wọn ọlọ́ọ̀pΓ‘ lΓ©tΓ­ nΓ­gbΓ kigbΓ  tΓ­ wọ́n bΓ‘ kẹ́ẹ́fΓ­n wọn.
"""Brother Arkadya Akopyan will have his final day in court on December 21, 2018."
"""December 21, 2018 ni ArÑkùnrin Arkadya Akopyan, mÑa fara hàn kẹ́yìn nílé ẹjọ́."
"We pray that our brothers and sisters in the Philippines will continue to trust in Jehovah, β€œour refuge and strength.”—Psalm 46:1-3."""
"Γ€dΓΊrΓ  wa ni pΓ© kΓ­ Γ¬gbΓ gbọ́ Γ wọn arΓ‘kΓΉnrin Γ tΓ wọn arΓ‘bΓ¬nrin wa lΓ³rΓ­lαΊΉΜ€-Γ¨dΓ¨ Philippines lΓ‘gbΓ‘ra sΓ­ i, kΓ³ sΓ¬ tΓΊbọ̀ dΓ‘ wọn lΓ³jΓΊ pΓ© JΓ¨hΓ³fΓ  ni Ọlọ́run β€œΓ Γ bΓ² wa Γ ti okun wa.”​—SÑàmΓΉ 46:​1-3."""
End of preview. Expand in Data Studio

Yoruba-English Translation Dataset

A curated parallel corpus for machine translation between English (en) and Yoruba (yo), designed for low-resource machine translation research and applications.

πŸ“Š Dataset Overview

  • Language Pair: English β†’ Yoruba (en-yo)
  • Total Sentence Pairs: 20,703
  • Quality Threshold: QE β‰₯ 0.6
  • Processing Date: September 22, 2025
  • Repository: amanuelbyte/yo-en-translation-dataset

🎯 Key Features

  • Low-Resource Optimized: Tailored quality thresholds for Yoruba language characteristics
  • Deduplicated: Extensive deduplication process removes redundant content
  • Multi-Domain: Covers diverse domains including technical, religious, educational, and general content
  • Quality Assured: All sentence pairs meet minimum Quality Estimation score of 0.6

πŸ“ˆ Dataset Statistics

Data Volume

  • Before Deduplication: 32,796 sentence pairs
  • After Deduplication: 20,703 sentence pairs
  • Deduplication Ratio: 36.9% reduction

Quality Metrics

  • Average QE Score: 0.68
  • Highest Quality Dataset: Tatoeba (QE: 0.7137)
  • Lowest Quality Dataset: Ubuntu (QE: 0.6452)

πŸ“š Data Sources

This dataset combines 20 high-quality sources:

Source Dataset Pairs QE Score Domain
wikimedia Wikipedia Articles 4,773 0.7035 General
mafand Mafand Dataset 3,985 0.6951 General
mafand-dev Mafand Development 3,985 0.6951 General
mafand-test Mafand Test Set 3,985 0.6951 General
AfriDocMT-health African Medical Documents 3,701 0.6721 Medical
menyo20k_mt-test Menyo20k Test Set 3,682 0.6947 General
menyo20k_mt-train Menyo20k Training 4,585 0.6997 General
menyo20k_mt-dev Menyo20k Development 1,432 0.6853 General
quran_multilingual_parallel Multilingual Quran 1,002 0.6568 Religious
ntrex News Articles 602 0.6780 News
Pontoon-Translations Mozilla Translations 553 0.6795 Technical
smol Smol Dataset 153 0.6694 General
GlobalVoices Global Voices 61 0.6769 News
opus-100 OPUS-100 Corpus 59 0.6557 General
opus-100-dev OPUS-100 Development 59 0.6557 General
opus-100-test OPUS-100 Test Set 59 0.6557 General
GNOME Software Localization 59 0.6557 Technical
Tatoeba Community Translations 21 0.7137 General
Weblate-Translations Weblate Platform 33 0.7056 General
Ubuntu Ubuntu Localization 7 0.6452 Technical

πŸ› οΈ Processing Pipeline

The dataset underwent comprehensive processing optimized for Yoruba:

  1. Rule-based Filtering: Length constraints, character validation
  2. Semantic Filtering: Sentence embedding similarity (threshold: 0.7)
  3. Language Detection: FastText + AfroLID models for accurate language identification
  4. Quality Estimation: Africomet QE model for translation quality scoring
  5. Sentence-level QE Filtering: Only pairs with QE β‰₯ 0.6 retained (optimized for Yoruba)
  6. Deduplication: 4-stage process removing identical and similar content

Deduplication Process

  1. Remove identical source-target pairs
  2. Remove duplicate (source, target) combinations
  3. Remove duplicate source sentences
  4. Remove duplicate target sentences

πŸ’Ύ Dataset Format

The dataset is available in Hugging Face datasets format with the following structure:

from datasets import load_dataset

dataset = load_dataset("amanuelbyte/yo-en-translation-dataset")
print(dataset)

# Dataset structure:
# DatasetDict({
#     "train": Dataset({
#         features: ['en', 'yo'],
#         num_rows: 20703
#     })
# })

Columns

  • en: English source text
  • yo: Yoruba target text

πŸ“– Usage Examples

Loading the Dataset

from datasets import load_dataset

# Load the dataset
dataset = load_dataset("amanuelbyte/yo-en-translation-dataset")

# Access the training split
train_data = dataset["train"]

# Get a sample
sample = train_data[0]
print(f"English: {sample['en']}")
print(f"Yoruba: {sample['yo']}")

For Machine Translation Training

# Prepare data for training
source_texts = train_data["en"]
target_texts = train_data["yo"]

# Statistics
print(f"Dataset size: {len(train_data)}")
print(f"Average source length: {sum(len(text.split()) for text in source_texts) / len(source_texts)".1f"}")
print(f"Average target length: {sum(len(text.split()) for text in target_texts) / len(target_texts)".1f"}")

πŸŽ“ Applications

This dataset is particularly suitable for:

  • Low-Resource MT: Training models for under-resourced Yoruba language
  • Cross-lingual Transfer: Multilingual NLP tasks involving African languages
  • Language Modeling: Pretraining language models for Yoruba
  • Quality Estimation Research: Studies on QE thresholds for low-resource languages
  • Linguistic Studies: Analysis of Yoruba-English language characteristics

πŸ” Quality Assessment

Dataset-Specific Insights

  • Optimized QE Threshold: 0.6 (vs 0.7 for higher-resource languages)
  • Quality Distribution: Reflects the challenges of Yoruba language processing
  • Source Diversity: Combines multiple domains for robust training data
  • Deduplication Effectiveness: 36.9% reduction indicates significant data cleaning

Quality Metrics Summary

  • Top Performing Sources: Tatoeba, Weblate-Translations, Wikimedia
  • Largest Contributors: Mafand datasets (11,955 pairs total)
  • Domain Coverage: Technical, religious, news, and general content

πŸ“„ License

This dataset is released under CC BY-SA 4.0 license. The individual source datasets maintain their original licenses.

🀝 Citation

If you use this dataset in your research, please cite:

@dataset{yo-en-translation-dataset-2025,
  title={Yoruba-English Translation Dataset},
  author={Amanuel Tewolde},
  year={2025},
  publisher={Hugging Face},
  journal={Hugging Face Hub},
  howpublished={\url{https://huggingface.co/amanuelbyte/yo-en-translation-dataset}}
}

πŸ“ž Contact

For questions or issues regarding this dataset, please contact:

  • Maintainer: Amanuel Tewolde
  • Email: [email protected]
  • Organization: Hugging Face Community

πŸ”— Related Resources


Note: This Yoruba dataset uses optimized quality thresholds (QE β‰₯ 0.6) compared to higher-resource languages, reflecting the challenges and characteristics of low-resource African language processing. The lower threshold ensures sufficient training data while maintaining quality standards appropriate for Yoruba language resources.

Downloads last month
26